Friday 20 October 2017

Lyrics: Oladips ft Reminisce - lalakukulala

oladips ft Reminisce - lalakukulala
Oladips ft Reminisce - lalakukulala 


[ CHORUS]
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala

Related: Harrysong - record of life lyrics

[ OLADIPS VERSE ]
Wo ko fu won lotu losi
Osha mo pe awon eleyi ko n shey oloshi
Songo ni yen e jo ema fu lobi
Mo ma kon e le yin o ma land ni igbobi
Otipe ti mo fe luwe ni be
Mo fe pon ke
Mo fe gegetige
N kan to shey titi ti ese fi ke
Omo to n jeje gbo gbo setetile
Useless bottom
Shaking by force
Emi lo ko gan
Is not my fault
Mo fe da koto si
Mo fe da golo si
Ti mi ba shet tan ma fi shakolo si
Mo fe ma de be ni aro kutu
Oya pamutuku

Suggested: Oritse femi ft olamide kelele lyrics

[ CHORUS ]
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala

Related: Djconsequences ft olamide - Assignment lyrics

[ REMINISCE VERSE ]
Ibile leso leso ni mo ba sa
Ti plug o ba wole lo converter
Engine me muna wa bi ti inverter
Oya kana mi da kalo montana
Ye lalakukulala
Je ki n pasapusupasa
Oda omo o ni bukata
Yeba ko tu wa wo pata
Idi araba lomo correct
Tan wifi re ki n connecti
Iwo omo yi oma collecti
Ki n gba le fun e room to leti
Oh ah
Ama yatayo ya
Ye pa
Le mo ogiri ko da

[ CHORUS ]
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Idi rabata
Anti alaba
To dabi alapa
Ma fi jo galala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala
Shey ki n la
Shey ki n la
Shey ki n la
Lalakukulala

SHARE THIS

Author:

0 comments: